Olorun to dara la wa n sin, Ohun la o ma dupe fun
Olorun to dara la wa n sin, Ohun la o ma dupe fun
O toh, o ye ka yin Oluwa,
O toh, o ye ka yin Baba wa,
Olorun to dara la wa n sin, Ohun la o ma dupe fun
A gbe o ga, Oluwa,
A tobi ju, Iwo lo to,
Olorun to dara la wa n sin, ohun la o ma dupe fun
A fiyin fun Oba wa aiyeraye.
Awon Angeli fiyin fun, Oba orun, gbogbo aye
Ko se ni to da bi Oba Orun,
Ko se ni to da bi Oba Orun,
Olorun to dara la wa n sin, Ohun la o ma dupe fun
No comments:
Post a Comment